Jẹnẹsisi 39:5 BM

5 Nígbà tí Pọtifari ti fi Josẹfu ṣe alabojuto ilé rẹ̀ ati gbogbo ohun ìní rẹ̀, OLUWA bẹ̀rẹ̀ sí bukun ìdílé Pọtifari, ará Ijipti náà, ati ohun gbogbo tí ó ní nítorí ti Josẹfu.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 39

Wo Jẹnẹsisi 39:5 ni o tọ