Jẹnẹsisi 39:6 BM

6 Nítorí náà, ó fi ohun gbogbo tí ó ní sí ìkáwọ́ Josẹfu níwọ̀n ìgbà tí ó wà pẹlu rẹ̀, kò sì bìkítà fún ohunkohun mọ́, àfi oúnjẹ tí ó ń jẹ.Josẹfu ṣígbọnlẹ̀, ó sì lẹ́wà.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 39

Wo Jẹnẹsisi 39:6 ni o tọ