26 Seti bí ọmọkunrin kan, ó sọ ọ́ ní Enọṣi. Nígbà náà ni àwọn eniyan bẹ̀rẹ̀ sí jọ́sìn ní orúkọ mímọ́ OLUWA.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 4
Wo Jẹnẹsisi 4:26 ni o tọ