1 Àkọsílẹ̀ ìran Adamu nìyí: Nígbà tí Ọlọrun dá eniyan, ó dá wọn ní àwòrán ara rẹ̀.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 5
Wo Jẹnẹsisi 5:1 ni o tọ