Jẹnẹsisi 40:3 BM

3 ó sì jù wọ́n sí ọgbà ẹ̀wọ̀n ní ilé olórí àwọn tí wọn ń ṣọ́ ààfin ninu ọgbà ẹ̀wọ̀n tí Josẹfu wà.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 40

Wo Jẹnẹsisi 40:3 ni o tọ