Jẹnẹsisi 40:4 BM

4 Alabojuto ọgbà ẹ̀wọ̀n náà fi wọ́n sábẹ́ àkóso Josẹfu, wọ́n sì wà ní ọgbà ẹ̀wọ̀n náà fún ìgbà díẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 40

Wo Jẹnẹsisi 40:4 ni o tọ