Jẹnẹsisi 41:18 BM

18 mo rí i tí àwọn mààlúù meje kan tí wọ́n sanra rọ̀pọ̀tọ̀ rọ̀pọ̀tọ̀, tí ara wọn sì ń dán, ti inú odò náà jáde wá, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí jẹ koríko létí odò.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 41

Wo Jẹnẹsisi 41:18 ni o tọ