19 Àwọn mààlúù meje mìíràn tún jáde láti inú odò náà, gbogbo wọn rù hangangan, wọ́n rí jàpàlà jàpàlà, n kò rí irú rẹ̀ rí ní gbogbo ilẹ̀ Ijipti.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 41
Wo Jẹnẹsisi 41:19 ni o tọ