Jẹnẹsisi 41:23 BM

23 Mo tún rí i tí ṣiiri ọkà meje mìíràn yọ lẹ́yìn wọn, wọ́n tínínrín, wọn kò sì ní ọmọ ninu rárá, nítorí afẹ́fẹ́ ìhà ìlà oòrùn ti pa ọlá mọ́ wọn lára.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 41

Wo Jẹnẹsisi 41:23 ni o tọ