Jẹnẹsisi 41:24 BM

24 Àwọn ṣiiri ọkà tí kò níláárí wọnyi gbé àwọn tí wọ́n dára mì. Mo rọ́ àwọn àlá mi fún àwọn adáhunṣe, ṣugbọn kò sí ẹnìkan tí ó lè túmọ̀ wọn fún mi.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 41

Wo Jẹnẹsisi 41:24 ni o tọ