25 Josẹfu sọ fún Farao, ó ní, “Ọ̀kan náà ni àlá mejeeji, Ọlọrun fi ohun tí ó fẹ́ ṣe han kabiyesi ni.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 41
Wo Jẹnẹsisi 41:25 ni o tọ