Jẹnẹsisi 41:55 BM

55 Nígbà tí oúnjẹ kò sí mọ́ ní gbogbo ilẹ̀ Ijipti, àwọn eniyan náà kígbe tọ Farao lọ fún oúnjẹ. Farao sọ fún gbogbo wọn pé, “Ẹ tọ Josẹfu lọ, ohunkohun tí ó bá wí fun yín ni kí ẹ ṣe.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 41

Wo Jẹnẹsisi 41:55 ni o tọ