Jẹnẹsisi 41:56 BM

56 Nígbà tí ìyàn náà tàn káàkiri gbogbo ilẹ̀, Josẹfu ṣí àwọn àká tí wọ́n kó oúnjẹ pamọ́ sí, ó ń ta oúnjẹ fún àwọn ará Ijipti, nítorí ìyàn náà mú gidigidi ní ilẹ̀ náà.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 41

Wo Jẹnẹsisi 41:56 ni o tọ