Jẹnẹsisi 41:57 BM

57 Gbogbo ayé ni ó sì ń wá sọ́dọ̀ Josẹfu ní Ijipti tí wọ́n wá ra oúnjẹ, nítorí pé ìyàn náà mú gidigidi ní gbogbo ayé.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 41

Wo Jẹnẹsisi 41:57 ni o tọ