Jẹnẹsisi 42:1 BM

1 Nígbà tí Jakọbu gbọ́ pé ọkà wà ní ilẹ̀ Ijipti, ó wí fún àwọn ọmọ rẹ̀ pé, “Kí ni ẹ̀ ń wo ara yín fún?

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 42

Wo Jẹnẹsisi 42:1 ni o tọ