Jẹnẹsisi 42:32 BM

32 Ọkunrin mejila ni àwa tí a jẹ́ ọmọ baba kan náà, ọ̀kan ninu wa ti kú, èyí tí ó kéré jù sì wà lọ́dọ̀ baba wa ní ilẹ̀ Kenaani.’

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 42

Wo Jẹnẹsisi 42:32 ni o tọ