Jẹnẹsisi 42:33 BM

33 Ọkunrin náà bá dáhùn pé, ohun tí yóo jẹ́ kí òun mọ̀ pé olóòótọ́ eniyan ni wá ni pé kí á fi ọ̀kan ninu wa sílẹ̀ lọ́dọ̀ òun, kí á gbé ọkà lọ sílé, kí ebi má baà pa ìdílé wa.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 42

Wo Jẹnẹsisi 42:33 ni o tọ