26 Nígbà tí Josẹfu wọlé, wọ́n mú ẹ̀bùn tí wọ́n mú bọ̀ fún un wọlé tọ̀ ọ́ lọ, wọ́n sì wólẹ̀ fún un, wọ́n dojúbolẹ̀.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 43
Wo Jẹnẹsisi 43:26 ni o tọ