27 Ó bèèrè alaafia wọn, ó ní, “Ṣé alaafia ni baba yín wà, arúgbó tí ẹ sọ̀rọ̀ rẹ̀ fún mi? Ṣé ó ṣì wà láàyè?”
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 43
Wo Jẹnẹsisi 43:27 ni o tọ