28 Wọ́n dá a lóhùn, wọ́n ní, “Baba wa, iranṣẹ rẹ ń bẹ láàyè, ó sì wà ní alaafia.” Wọ́n tẹríba, wọ́n bu ọlá fún un.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 43
Wo Jẹnẹsisi 43:28 ni o tọ