Jẹnẹsisi 43:29 BM

29 Ojú tí ó gbé sókè, ó rí Bẹnjamini ọmọ ìyá rẹ̀, ó bá bèèrè pé, “Ṣé arakunrin yín tí í ṣe àbíkẹ́yìn tí ẹ wí nìyí? Kí Ọlọrun fi ojurere wò ọ́, ọmọ mi.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 43

Wo Jẹnẹsisi 43:29 ni o tọ