Jẹnẹsisi 46:3 BM

3 Ọlọrun wí pé, “Èmi ni Ọlọrun baba rẹ, má fòyà rárá láti lọ sí Ijipti, nítorí pé n óo sọ ọ́ di orílẹ̀-èdè ńlá níbẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 46

Wo Jẹnẹsisi 46:3 ni o tọ