Jẹnẹsisi 46:4 BM

4 N óo bá ọ lọ sí Ijipti, n óo sì tún mú ọ pada wá, ọwọ́ Josẹfu ni o óo sì dákẹ́ sí.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 46

Wo Jẹnẹsisi 46:4 ni o tọ