Jẹnẹsisi 47:26 BM

26 Bẹ́ẹ̀ ni Josẹfu ṣe sọ ọ́ di òfin ní ilẹ̀ Ijipti, tí ó sì wà títí di òní olónìí pé ìdámárùn-ún gbogbo ìkórè oko jẹ́ ti Farao, ati pé ilẹ̀ àwọn babalóòṣà nìkan ni kì í ṣe ti Farao.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 47

Wo Jẹnẹsisi 47:26 ni o tọ