27 Israẹli ń gbé ilẹ̀ Ijipti, ní Goṣeni, wọ́n sì ní ọpọlọpọ ohun ìní níbẹ̀, wọ́n bímọ lémọ, wọ́n sì pọ̀ sí i gidigidi.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 47
Wo Jẹnẹsisi 47:27 ni o tọ