28 Ọdún mẹtadinlogun ni Jakọbu gbé sí i ní ilẹ̀ Ijipti, gbogbo ọdún tí ó gbé láyé sì jẹ́ ọdún mẹtadinlaadọjọ (147).
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 47
Wo Jẹnẹsisi 47:28 ni o tọ