Jẹnẹsisi 49:3 BM

3 Reubẹni, ìwọ ni àkọ́bí mi,agbára mi, ati àkọ́so èso agbára mi,ìwọ tí o ní ìgbéraga jùlọ,tí o sì lágbára jùlọ ninu àwọn ọmọ mi.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 49

Wo Jẹnẹsisi 49:3 ni o tọ