Jẹnẹsisi 49:4 BM

4 Ìwọ tí o dàbí ìkún omi tí ń bì síwá sẹ́yìn,o kò ní jẹ́ olórí, nítorí pé o ti bá obinrin mi lòpọ̀,o sì ti sọ ibùsùn èmi baba rẹ di aláìmọ́.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 49

Wo Jẹnẹsisi 49:4 ni o tọ