25 Josẹfu sì mú kí àwọn ọmọ Israẹli búra fún un pé, nígbà tí Ọlọrun bá mú wọn pada sí ilẹ̀ Kenaani, wọn yóo kó egungun òun lọ́wọ́ lọ.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 50
Wo Jẹnẹsisi 50:25 ni o tọ