Jẹnẹsisi 50:26 BM

26 Josẹfu kú nígbà tí ó di ẹni aadọfa (110) ọdún. Wọ́n fi òògùn tọ́jú òkú rẹ̀ kí ó má baà bàjẹ́, wọ́n sì tẹ́ ẹ sinu pósí ní ilẹ̀ Ijipti.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 50

Wo Jẹnẹsisi 50:26 ni o tọ