1 Nígbà tí ó yá OLUWA sọ fún Noa pé, “Wọ inú ọkọ̀ lọ, ìwọ ati àwọn ará ilé rẹ, nítorí pé ìwọ nìkan ni o jẹ́ olódodo sí mi ní gbogbo ayé.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 7
Wo Jẹnẹsisi 7:1 ni o tọ