Jẹnẹsisi 7:2 BM

2 Ninu gbogbo ẹran tí ó bá jẹ́ mímọ́, mú wọn ní takọ-tabo, meje meje, ṣugbọn ninu gbogbo ẹran tí kò bá jẹ́ mímọ́, mú akọ kan ati abo kan.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 7

Wo Jẹnẹsisi 7:2 ni o tọ