Jẹnẹsisi 9:1 BM

1 Ọlọrun súre fún Noa ati àwọn ọmọ rẹ̀, ó ní, “Ẹ máa bímọ lémọ, kí ẹ máa pọ̀ sí i, kí ẹ sì kún gbogbo ayé.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 9

Wo Jẹnẹsisi 9:1 ni o tọ