2. Kro 18:34 YCE

34 Ija na si pọ̀ li ọjọ na: pẹlupẹlu ọba Israeli duro ninu kẹkẹ́ rẹ̀ kọju si awọn ara Siria titi di aṣãlẹ: o si kú li akokò ìwọ õrun.

Ka pipe ipin 2. Kro 18

Wo 2. Kro 18:34 ni o tọ