2. Kro 21:7 YCE

7 Ṣugbọn Oluwa kò fẹ ipa ile Dafidi run, nitori majẹmu ti o ti ba Dafidi da, ati bi o ti ṣe ileri lati fun u ni imọlẹ kan ati fun awọn ọmọ rẹ̀ lailai.

Ka pipe ipin 2. Kro 21

Wo 2. Kro 21:7 ni o tọ