2. Kro 25:12 YCE

12 Ati ẹgbãrun alãye li awọn ọmọ Juda kó ni igbekun lọ, nwọn si mu wọn lọ si òke apata na, nwọn si tãri wọn silẹ lati òke apata na, nwọn si fọ́ tũtu.

Ka pipe ipin 2. Kro 25

Wo 2. Kro 25:12 ni o tọ