2. Kro 25:15 YCE

15 Nitorina ni ibinu Oluwa ru si Amasiah, o si ran woli kan si i, ti o wi fun u pe, Ẽṣe ti iwọ fi nwá oriṣa awọn enia na, ti kò le gbà awọn enia wọn lọwọ rẹ?

Ka pipe ipin 2. Kro 25

Wo 2. Kro 25:15 ni o tọ