2. Kro 25:7 YCE

7 Ṣugbọn enia Ọlọrun kan tọ̀ ọ wá, wipe, Ọba, máṣe jẹ ki ogun Israeli ki o ba ọ lọ: nitoriti Oluwa kò wà pẹlu Israeli, ani gbogbo awọn ọmọ Efraimu.

Ka pipe ipin 2. Kro 25

Wo 2. Kro 25:7 ni o tọ