2. Kro 29:11 YCE

11 Ẹnyin ọmọ mi, ẹ máṣe jafara nisisiyi: nitori ti Oluwa ti yàn nyin lati duro niwaju rẹ̀, lati sìn i, ati ki ẹnyin ki o mã ṣe iranṣẹ fun u, ki ẹ si mã sun turari.

Ka pipe ipin 2. Kro 29

Wo 2. Kro 29:11 ni o tọ