2. Kro 30:12 YCE

12 Ni Judah pẹlu, ọwọ Ọlọrun wà lati fun wọn li ọkàn kan lati pa ofin ọba mọ́ ati ti awọn ijoye, nipa ọ̀rọ Oluwa.

Ka pipe ipin 2. Kro 30

Wo 2. Kro 30:12 ni o tọ