7 Gbogbo awọn enia ti o kù ninu awọn ara Hitti, ati awọn Amori, ati awọn Peresi, ati awọn Hifi ati awọn Jebusi, ti kì iṣe ti inu ọmọ Israeli.
Ka pipe ipin 2. Kro 8
Wo 2. Kro 8:7 ni o tọ