2. Kro 8:8 YCE

8 Ninu awọn ọmọ wọn, ti a ṣẹkù silẹ lẹhin wọn ni ilẹ na, ti awọn ọmọ Israeli kò run kuro, awọn ni Solomoni bu iṣẹ-ìrú fun titi o fi di oni yi.

Ka pipe ipin 2. Kro 8

Wo 2. Kro 8:8 ni o tọ