9 Ṣugbọn ninu awọn ọmọ Israeli ni Solomoni kò fi ṣe ọmọ-ọdọ fun iṣẹ rẹ̀; nitori awọn li ọga-ogun ati olori awọn onikẹkẹ́ rẹ̀ ati awọn kẹkẹ́ rẹ̀, ati awọn ẹlẹṣin rẹ̀.
Ka pipe ipin 2. Kro 8
Wo 2. Kro 8:9 ni o tọ