Òwe 27:18 BMY

18 Ẹni tí ó tọ́jú igi ọ̀pọ̀tọ́ yóò jẹ èṣo rẹ̀ẹni tí ó sì fojú tó ọ̀gá rẹ̀ yóò gba ọlá.

Ka pipe ipin Òwe 27

Wo Òwe 27:18 ni o tọ