Òwe 29:14 BMY

14 Bí ọba kan bá ń ṣe ìdájọ́ talákà pẹ̀lú òtítọ́ìtẹ́ ìjọba rẹ yóò fìdí múlẹ̀ nígbà gbogbo.

Ka pipe ipin Òwe 29

Wo Òwe 29:14 ni o tọ