Òwe 29:15 BMY

15 Ọ̀pá ìbániwí ń fún ni ní ọgbọ́nṣùgbọ́n ọmọ tí a fi sílẹ̀ fúnra rẹ̀ a dójú ti ìyá rẹ̀.

Ka pipe ipin Òwe 29

Wo Òwe 29:15 ni o tọ