Ẹkisodu 1:11 BM

11 Nítorí náà, wọ́n yan àwọn akóniṣiṣẹ́ láti ni wọ́n lára pẹlu iṣẹ́ àṣekára. Wọ́n lò wọ́n láti kọ́ ìlú Pitomi ati Ramesesi tíí ṣe àwọn ìlú ìṣúra fún Farao.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 1

Wo Ẹkisodu 1:11 ni o tọ