15 Nígbà tí ó yá, ọba Ijipti pe àwọn obinrin Heberu tí wọ́n ń gbẹ̀bí, tí orúkọ wọn ń jẹ́ Ṣifira ati Pua, ó sọ fún wọn pé,
Ka pipe ipin Ẹkisodu 1
Wo Ẹkisodu 1:15 ni o tọ