9 Ọba yìí sọ fún àwọn eniyan rẹ̀ pé, “Ẹ wò bí àwọn ọmọ Israẹli wọnyi ti pọ̀ tó, tí wọ́n sì lágbára jù wá lọ.
Ka pipe ipin Ẹkisodu 1
Wo Ẹkisodu 1:9 ni o tọ