Ẹkisodu 10:11 BM

11 N ò gbà! Ẹ̀yin ọkunrin nìkan ni kí ẹ lọ sin OLUWA; nítorí pé bẹ́ẹ̀ gan-an ni ẹ fẹ́ àbí?” Wọ́n bá lé wọn jáde kúrò níwájú Farao.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 10

Wo Ẹkisodu 10:11 ni o tọ